Lójijì Heng Lee bẹ̀rẹ̀ síí ní ìmọ̀lára tí ó ṣàjèjì, nítorí náà ó wá láti rí aláwo ní agbègbè, tí ó jẹ́ ìbátan rẹ̀. Ó ṣe àwọn àyẹ̀wò díẹ̀ ó sì pinnu pé Heng kò ní ẹ̀jẹ̀, ṣùgbọ́n báwo ni yóò ti sọ fún ìdílé rẹ, kínni wọn yóò sì ṣe nípa rẹ̀?
¡Compre este libro electrónico y obtenga 1 más GRATIS!
Formato EPUB ● Páginas 322 ● ISBN 9788835416753 ● Tamaño de archivo 0.4 MB ● Traductor Sola Agboola ● Editorial Tektime ● País GB ● Publicado 2021 ● Descargable 24 meses ● Divisa EUR ● ID 7731870 ● Protección de copia sin